UTME CBT FREE Practice Test – Yoruba Language – Set 3


Hello and Welcome to UTME CBT FREE Practice Test - Yoruba Language - Set 3

  1. You are to attempt 35 Objectives Questions ONLY for  20 minutes.
  2. Supply Your Full Name in the text box below and begin immediately.
  3. Your time starts NOW!
Full Name (Surname First):
Ka àwôn àyôkà ìsàlê yìí, Kí o sì dáhùn àwôn ìbéèrè tí ó têlé wôn.

I
Olújôkë jë akëkõö ni ilé-êkö girama kan ní ìlú Êpë. Lará, Bölá àti Ìyábõ jë õrëminú rê. Ní ìbêrê Olújôkë þ se ômô jëjë, kì í kôjá ayé rê. Kò pë, kò jìnnà, lômô bá di àgùntàn tí ó bá ajá rìn tí þ jç ìgbë. Lará àti Bölá ni gbogbo ilé-êkö mõ pêlú ìrìn àrè, kí wön tó bojú wò, Ìyábõ ti di alábàárìn wôn. Kàyéfì, ômô tí ò le rúnta kúnná yçn! Ló gba çnu olùkö àti àwôn akëkõö.

Alàgbà Bölömôpë tí í ÿe olùkö àgbà ilé-êkö náà a máa pàrôwà sí àwôn akëkõö rê nígbà gbogbo, ni õpõ ìgbà a tún rô àwôn olùkö láti máa fi õrõ Ôlörun bö àwôn ômô náà yó. ßùgbön bí a gún iyán nínú ewé tí a ro ôkà nínú eèpo-êpà, eni máa yó á kúkú yó ni õrõ õhún dà. Kí Jôkë tó gbêyà ni olùkö àgbà ti fàá lé olùkö àÿà àti ìÿe löwö láti máa bójú tó o.

Êwê, nígbà tí õrõ ômô náà kò yé olùkö àgbà mö, ni ó bá kõwè sí õgbëni àti ìyáàfin Agbájé tí wön þ ÿe òbí Jôkë láti fi õrõ ômô wôn tó wôn létí. Àmö àtijç, àtimu kò fi àyè sílè ni ohun tí wôn þ wí, wön ti gbàgbé pé bi ìdí bá bà jë tónídìí níí dà. Êyìn-ò-rçyìn, Jôkë àti àwôn çmêwà rê gbé jonbo níbi ojú-mi-là tí wôn þ bá kiri níbi tí àwôn tòkunbõ kán pe àpèjo.

Nílé ìgbafë tí wön fi ìpè sí ni àwôn olófòófó `ilú ti ta àwôn agbèföba lólobó pé àwôn õdaràn kan tí wön dìgbòlu ilé ìfowópamö ìlú Êpë ní ôjö díê sëyìn þ ÿôdún owó ní ilé ìgbafë Kúlúbö. Kété tí àwôn agbófinró gbö ni wön bá ta möra tí wön sì ya bo ibi àpèjo náà. Gbogbo çni tí wön bá ní ibi ayeye õhún ni wön fí òfin gbé wön dé iwájú adájö. Lëyìn õpõ atótónu lënu àwôn agbçjörò tõtùntòsi, adájö fi êsùn ìpanilëkúnjayé kan àwôn olùpe àpèjê náà pêlú ìdájö ikú. Ilé-çjö sì fi êsùn ìgbódegbà fún àwôn ôlöÿà kan `awôn õrë mêrin pêlú êwõn ôdún mökànlélógún àti iÿë àÿekára.

1. Àwôn òbí Olújôkë dágunlá ìpè alàgbà Bölömôpé nítorí

A. iÿë    B. àìráyè    C. àìlówó    D. ìròjú.

2. Irù ènìyàn wo ni àwôn olùpe àpèjç jë?

A. Agbèföba    B. Ôlöÿà    C. Olùkö    D. Akëkõö.

3. Esùn tí ilè-ejõ fi kan Olùjôkë àti àwôn emêwà rê ni

A. ìgbódegbà fùn àwôn adigunjalè
B. ìgbódegbà fùn àwôn agbófinró
C. ìpanìyan àti ìdigunjalè
D. ìdàlúrú àti ìpanilëkún

4. Ibi tí Olújôkë àti àwôn õrë rê parí ayé wôn sí ni

A. ôgbà ôlöpàá   B. ôgbà êwõn   C. ilé ôkô   D. ilé-êkö

5. gbé jonbo túmõ sí

A. wô wàhálà    B. jí jonbo gbé   C. mô ìwôn ara çni   D. àìbalè.II
Çni a wí fún Ôba jë ó gbö.
Èèyàn táa fö fún Elédùà jë ó gbá.
Kí ní þ bç nínú ayé táa wayé mörí.
Kí ní þ bç ní dúníyàn táa sayé dàwá à lô.
Ilé-ayé ilé asán, 5
Ilé-ayé à-fôwö-bà-fiílê.
Ç jë á dögbön jayé,
Kí wön má ba à jçwá máyé.
Ç bá jë á fôgbön lògbà, kígbà má jù wá nù
Kòókòó, jàn-án-jàn-án ilé-ayé ló mô. 10
Kò sóhun táa mú wáyé,
Bëê la ò ní mú ohun kan lô ní dúníyàn.
Òní Pôtá, õla Kàfàýÿà.
Ijö a bá kú ló tán
Aà ! Kí lá þ walé ayé möyà sí? 15
Báa lówó löwö a máa kú,
Bá ó sì ní õrun là þ rè
Bí a ìí báá kú ará ìgbàun dà?
Oníÿë ôwö þ sáré kó kówó ná,
Alákõwè þ sáré àtikówó mì. 20
Báa bá lówó õhún tán,
Emi la fë fi ÿe?
ße bëç rárá òkè-õhún,
Tó kówókówó,
Tó fàyà wö,
Tó fìdí fà,
Níjö ikú dé kí ló mú lô
Níjö Elédùà bèèrè êmí,
Kí ló rí jù sápò?
Ç bá jë á rôra wówó ká lè rówó ná.
Ç jé á fi sùúrù wá náírà,
Këmìín çni lè gùn.
Sùúrù ló gbà kò gba kólekóle.
Gbogbo çni bá kánjú wówó,
Á kánjú rõrun alákeji
Ç yéé ÿe wàduwadù ní dúníyàn.

6. Àrôwa tí akéwì yìí þ fi ewì rë pa ni pé

A. ká yéé fipá wówó
B. kò sóhun tó burú nínú fàyàwö
C. gbogbo wa lowó tö sí
D. kárí ayé ni ikú.

7. Óní Pôtá õla Kàfàýÿà túmõ sí

A. rírin ìrìn-àjò ojoojúmó
B. fífi Pôtá àti Kàfàýÿà ÿebùgbé
C. àìfúnra-çni nísinmi
D. õnà àtijç àtimu.

8. Lójú akéwì yìí ilé-ayé túmõ sí pè

A. Ilé irô ni    B. Kì í se àwáìlô     C. ibùgbé láéláé ni    D. kò tóö kú fún.

9. Bí a ìí báá kú ará ìgbàun dà ? túmò sí

A. gbogbo ayé l’o ti kú tán
B. kò sëni tí kò ní í kú
C. àwôn ará àtijô ÿì þ bç láyé
D. ìbéèrè nípa ará àtijö.

10. Ní èrò akéwì yìí, ohun tí a fi þ gbélé ayé ni

A. sùúrù    B. owó    C. ìtëlörùn    D. kìràkìtà.ÈDÈ

11. Fáwëlì àhánudíêpè iwájú pçrçsç ni

A. [a]    B. [ε]    C. [e]    D. [u]

12. Fi àmì ohùn tí ó tönà sórí ALAPAANDÇDÇ

A. ALÁPAÁNDÇDÇ
B. ALÁPÀÁNDÇDÇ
C. ALAPÁÀNDÇDÇ
D. ALAPÁÀÞDÇDÇ.

13. Sílébù mélòó ló wà nínu GÕÝGÕßÚ?

A. Mérin    B. Mëta    C. Méjì    D. Òkan.

14. Irú àrànmö wo ló wáyé nínú OßOOßÙ?

A. Àrànmö çlëbç    B. Àrànmëyìn    C. Àrànmö afòró    D. Àrànmöwájú.

15. A yá àlùbösà lò láti inú èdè?

A. Haúsá    B. Èbìrà    C. Lárúbáwá    D. Gíríkì.

16. Õrõ àìÿêdá ni

A. iÿë    B. ìka    C. ijó    D. ìfë

17. Möfíìmù afarahç mélòó ló wà nínú aláìgbön?

A. Mérin    B. Mëta    C. Méjì    D. Õkan.

18. Nínú Mo ra ilé títóbi, títóbi jë êyán

A. aÿòýkà    B. aÿàpèjúwe    C. oníbàátan    D. aÿàfihàn.

19. Nínú Aÿô funfun bálaú yçn ni mo rà, funfun báláu yçn jë àpólà

A. õrõ-ìÿe B. õrõ-àpèjúwe C. õrõ-orúkô D. õrõ-atökùn.

20. Èwo nínú ìwõnyí ni gbólóhùn alátçnumö?

A. Adé ni ó wá
B. Adé kò wá
C. Adé wá lánàá
D. Adé wá ÿùgbön kò dùró.

21. Báyõ tì lô jë àpççrç ibá-ìÿêlê

A. aÿetán ìparí    B. àdáwà    C. àìÿetán bárakú    D. aÿetán ìbêrê.

22. Èwo ló tõnà ní ìlànà àkôtö òde-òní nínú ìwõnyí?

A. Nkan þlá ÿçlê nígbàti nwôn lô
B. Nkan þlá ÿçlê ní gbàtí wön lô
C. Nýkan ýlà ÿçlê nígbà tí wön lô
D. Nýkan þ la ÿçlê nígbàtí nwôn lô

23. Àkôtö tí ó tònà ní

A. afé rí ô bí o bádé
B. a fé ríô bí o bádé
C. a fé rí ô bí o bá dé
D. a férí ô bí o bá dé.

24. Tell it to the wind túmõ sí

A. Sô ö sí afëfë
B. Sô ö fún afëfë
C. Wá irö mìíràn pa
D. ßô õrõ náà fún çlòmíràn.

25. My dark days are over túmò si

A. Ôjö dúdú mi ti dópin
B. Ìÿòro ayé mi dópin
C. Òkùkùn ayè mi ti dópin
D. Ôjö burúkú mi ti dopin.ÌßÊßE

26. Èwo ni ohun-èlò fún bíbô Õrúnmìlà nínú ìwõnyí?

A. Èkuru     B. Obì     C. Êwà     D. Ewúrë.

27. Gëgë bí èrò Yorùbá, Òrìÿà tó þ ÿiÿë bí ôlöpàà níwájú Olódùmarè ni

A. Ôbàtálá    B. Ògún    C. Èÿù    D. ßõnpõnná.

28. Ökan lára ojúÿe àwôn õdö ní ayé àtijô ni láti?

A. tún ààfin ôba ÿe    B. máa ÿiÿé agbê    C. jë àwòrò òrìÿà    D. fìyà jç arúfin.

29. ‘Ômô aÿíjú apó pìrí
Da igba ôfà söfun
A-põfun-jõyõ
Da igba ôfà sílê’

Ta ni à þkì báyìí nínú olóyè ogun wõnyí?

A. Ààre-õnà-kakaýfò    B. Oníkòyí    C. Jagùnnà    D. Alápinni

30. Õnà tí obìnrin þ gbá láti di ìyáálé ni

A. ôjö orí rê    B. àtètè délé ôkô    C. ìfë bale    D. iye ômô.

31. Láàrin àwôn Yorùbá, èyí tí ó jë àpínmógún nínú ìwõnyi ni

A. ìyàwó-ilé    B. ômô-àlè    C. ômô-õdõ    D. akótilétà-ômô

32. Òkú çni tí àwôn Yorùbá máa þ sin sínú ìgbó ni

A. atiro    B. ôdç    C. adëtê    D. wèrè.

33. Afitirê-sílê-gbö-tçni-çlëni
Irú ìwà ômôlúàbí tí ìpèdè yìí fi hàn ni

A. õyàyà    B. ìgboyà    C. inú-rere    D. iÿë sí õrë.

34. Irú ìwà wo ni ômôdé tí ó gba çrú löwö àgbà fi hàn?

A. Ìbõwõ    B. Inú rere    C. Ìgboyà    D. Ìmoore.

35. Ìwà êtö ômôlúàbí ni

A. ojo    B. ìmëlë    C. ìgboyà    D. àrífín.

GREAT! You finished before the expiration of the 20 minutes allotted to you. You may want to preview before submission, else, Click the submit button below to see your score

To submit your quiz and see your score/performance report; Make sure you supply your Full Name in the form above.

Unable to submit your quiz? Kindly Click Here To Retake UTME CBT FREE Practice Test - Yoruba Language - Set 3. Make sure you supply your Full Name before submission.
0 Comments

Leave a Reply

Avatar placeholder

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.

Online Learning and Assessment Portal for Nigerian Students
error: Content is protected !!