Ka àwôn àyôkà ìsàlê yìí, Kí o sì dáhùn àwôn ìbéèrè tí ó têlé wôn.
I
Babárìndé nífêë Fôláÿadé púpõ. Fôláÿadé náà sì rèé, òrékelëwà ômôge,
çlëyinjú-çgë, çlërin-ín êyç! Òun náà sì dá ìfë yìí padà pêlú ayõ àti
ìdùnnú. ßùgbön bàbá Fôláÿadé ni igi wörökö tí þ da iná rú nídìí õrõ
yìí: ó kórìíra Babárìndé nítorí pé ó kà á sí òtòÿì ènìyàn.Bëê ômôlójú
rê sì ni Fôláÿadé í ÿe. Baba gbàgbö pé bí ômô òun bá fë Babárìndé,
inú ìyà ni tôkôtaya wôn yóò wà.
Kì í kúkú í ÿe pé Babárìndé jë tálákà bëê náà: ó þ ÿiÿë gëgë bí òÿìÿë
kékeré nílé-iÿë þlá kan, bëê ni kò sì tôrô jç, ÿùgbön ó kàn jë pé kò
lówó tó Ayõkúnlé Atáyéwá, oníÿòwò kan tí baba Fôláÿadé fë kí ômô
rê fë. Ìyá Fôláÿadé náà sì rèé, ibi tí ôkô rê bá tê sí ni òun náà þ tê
sí. ßé ojúbõrõ kö ni a sì fi þ gbômô löwö èkùrö: àwôn òbí Fôláÿadé
fi toògùn-toògùn fa ômô wôn fún Ayõkúnlé Atáyéwá ÿaya.
Babárìndé banújë nídìí õrõ yìí, êdùn-ôkàn sì ni Fôláÿadé gbé wôlé
ôkô.
Ôjö þ gorí ôjö, ôdún þ gorí ôdún, bëê ni ìgbà sì þ rékôjá lo. Fôláÿadé
bí akô, ó bi abo nílé ôkô, ÿúgbön nýkan ò lô déédé fún ôkô rê mö
lënu òwò rè. Àwôn oníbodè ti gbësê lé ôjà rê tó jë çgbêlëgbê náírà.
Ó yáwó nílé-ìfowópamö, ÿùgbön kò rí i san padà. Àwôn báýkì bá
gba ilé, ôkõ àti àwôn dúkìá rê mìíràn. Àtijç-àtimu wá di ìÿòro fún
òun àti ìyàwó rê àti àwon ômô wôn pêlú.
Níhà kejì, Babárìndé náà ti gbéyàwó, ó sì tí bímô. Lënu iÿë rê wàyìí,
ó ti di õgá, orí sì ti sún un sölá. Àwôn òbí Fôláÿadé wá þ wò sùnùn,
wön rí i bí ìgbé-ayé Ayõkúnlé Atáyéwá ÿe þ lô, wön sì tún wo
ti Fôláÿadé ômô wôn, bákan náà ni wön sì þ gbókèèrè wo ti
Babárìndé bó ÿe þ dùn sí i fún un. Wön wá fika àbámò bônu: iwájú
ò ÿeé lô, èyìn ò sì ÿeé padà sí fún wôn. Babárìndé, eni tí wôn rò pé
kò lè pàgö ló wá dçni tí þ kölé aláruru. Ó wá hàn kedere sí wôn pé
çni tí yóò dôlölà löla, orí ló mõ ön.
1. Êkö pàtàkì tí àyôkà yìí köni ni pé
A. oògùn máa þ jë
B. êda kò láròpin
C. agbaniláya ò rore síni
D. kí a máa fõrõ rora çni wò.
0 Comments