Hello and Welcome to UTME CBT FREE Practice Test - Yoruba Language - Set 1

  1. You are to attempt 35 Objectives Questions ONLY for  20 minutes.
  2. Supply Your Full Name in the text box below and begin immediately.
  3. Your time starts NOW!
Full Name (Surname First):

Ka àwôn àyôkà ìsàlê yìí, Kí o sì dáhùn àwôn ìbéèrè tí ó têlé wôn.

I
Ôba Fadérera ní oko kòkó àti oko obì, ó ní oko iÿu àti oko òwú, ilá inú oko rè ni
gbogbo ìlú gbójú lé, iÿu àkùrõ rê níí kökö yôjú sí ôjà. Oko ôba gbòòrò púpõ.Sé ìgbà
púpõ ni õpõlôpõ ènìyàn þ lô láti ÿiÿç õfë fún ôba. Ôba tún fi ôgbôn ÿe é tó bëê tí irè
oko rê kò wön tó ti çlòmíràn.

Ôba Fadérera bí ômôkùnrin kan tí ó fëràn púpõ. Ômô ôba yìí kì í ÿe iÿë kankan,
àfi ki ó máa ÿiré nínu ôgbà baba rê. Àwôn ìránÿë põ láti fún un ní gbogbo ohun tí ó
bá þ fë. Aÿô tuntun ni ômô ôba þ wõ ní ojoojúmö. Ôba kë ômô náà bí çyin ojú, ó kë
pêlú ohun ìní àti ìránÿë.

Ohun kan wá jë êdùn ôkàn àwôn ará ìlú Êyìn-Õla.

Ohun náà ni pé, ìkòokò a máa dédé wô ìlú láti gbé ewúrë tàbí àgùntàn wôn lô. Ní ìgbà púpõ ni àwôn ará ìlú ti lô ké bá ôba kí ó bá àwôn yanjú õràn tí ó dé bá wôn. Nígbà tí ó ÿe wàyí o, àwôn ìkòokò pàápàá wá tún ara mú, wön bêrê sí í gbé àwôn ômô ará ìlú

Êyìn-õla. Àwôn ìlú tún ké lô sí õdõ õba, ÿùgbön ôba kò ka õrõ náà sí rárá.
Ní ôjö kan nígbà tí ômô ôba Fadérera àti àwôn çmêwà bàbá rê þ ÿiré lórí pápá tí
ó wà lëbàá ààfin, ìkòokò þlá kan yô sí wôn, ó sì gbé ômô ôba lô ráúráú. Nígbà tí ôba gbö ohun tí ó ÿçlê, ó kígbe ní ohùn rara.

Õrõ náà wá ya gbogbo ìlú lënu nítorí pé ôba pàÿç lësêkçsê pé kí gbogbo àwôn ôdç
atamátàsé ìlú jáde, kí wön sì pa gbogbo ìkòokò tí ó wà agbègbè náà. Sùgbön ìkòokò tí pa ômô ôba Fadérera jç. Êpa kò bóró mö.

1. Kí ni ó fún Ôba Fadérera lólìkí?

A. Ìwà rere rê    B. Oko iÿu rê    C. Çwà rê    D. Irè oko rê.


2. Êdùn ôkàn àwôn ará ìlú Êyìn-Õla ni

A. àìsí òjò
B. ìkòokò tí þ dààmú ìlú
C. àìsí omi
D. iÿë õfë ÿíÿe lóko ôba.


3. Asõtàn fi Ôba Fadérera hàn bíi

A. apànìyàn    B. onínú rere    C. aláìbìkítà    D. aláìláàánú.


4. Ohun ti ó mú irè oko ôba tà ju ti ará ìlú lô ni pé

A. ôba gbön jù wön lô
B. irè oko ôba kò wön
C. iÿu oko ôba tóbi ju ti ará ìlú
D. ôba ní agbára.


5. Ìtumõ ráúráú nínú àyôkà yìí ni

A. tipátipá    B. kíakía    C. pátápátá    D. tôlàtôlà
II
Orí loníÿe, êdá làyànmö.
Àkúnlêyàn òun ni àdáyébá.
A délé ayé tán ojú þ kán gbogbo wa;
Orí níí ÿatökùn fúnni.
Ìgbà ti ara ènìyàn kò yá,
Òògùn ló lôjö kan ìpönjú,
Orí ló lôjö gbogbo.
Orí çni làwúre çni;
Orí ló yç kénìyàn ó sìn.
Báa bá wálé ayé táa lówó löwö,
Àyànmö ni.
Bí a sì wà lókèèrè, táyé þ yö wa wò níkõrõ,
ßebí orí ló sohun gbogbo.
Ohun ti Táyé þ ÿe tó fi lówó löwö,
Òun ni Këhìndé ÿe tó dolòsì.
Ç má fõrõ àyànmö wéra.
Nítori ohun ti a yàn, õtõõtõ ni,
Báyé bá yçni, ÿebí orí inú çni ni.
Báa bá dènìyàn þlá, ohun táa dì mö kádàrá ni.
Ohun ti a rù lórí, látòde õrun wá ni.
Kò séèyàn ti í paÿô àgùntàn-án dà.
Táyé bá ÿelá tílá fi kó,
Téniyàn ÿekàn tíkàn bá wêwù êjê
Táyé náà bá tún taÿô ìjímèrè bepo
Ká rántí pé ohun táa mú wáyé látòde õrun ni
Kò sëni pa Lágbájá,
Kò sëni pa Làkáÿègbè;
Ó ti wà nínú àkôölê rê ni.
Orí jà ó joògùn
Orí là bá máa bô löjö gbogbo
Orí ni ààbò çni,
Kò sórìÿà ti þ gbeni lëyìn orí çni.
Bénìyàn bá ní wàhálà, orí ni yóò ké sí.
Máà bënìkan sô,
Nítorí ènìyàn kò fêni förõ, à forí çni.

6. Kókó inú ewì yìí ni pé

A. Orí tó ti bàjë kò ÿeé túnÿe
B. ohun orí ëní yàn ní í yôni lënu
C. àyànmö kò gbóògùn
D. àdáyébá nìpín çni.


7. Ìtumõ kádàrá nínú ewì yìí ni

A. ìpín    B. ìwá    C. ìgbésí-ayé    D. ilé-ayé.


8. Ìdí ti akéwì fi ní ká bórí sô ká máà bënìkan sô ni pé

A. ènìyàn kò fëni förõ
B. a kò mçni tó fëni dénú
C. çnìkan kò báni yan orí çni
D. orí ni êdá sìn wáyé.


9. Nínú ìlà 14-15, ohun ti akéwì sô nípa Táyé àti Këhìndé ni pé

A. ômô ìyá kan niwön
B. orí õkan sunwõn ju èkejì lô
C. àkôölê oníkálùkù, õtõõtõ ni
D. Táyé kò lè ran Këhìndé löwö


10. A délé ayé tán ojú þ kán gbogbo wa túmõ sí pé

A. êdá þ fi wàdùwàdù ÿe nýkan
B. êdá þ lépa ohun ti kò yàn látõrun
C. ojú êdá kò gbébìkan
D. ìÿòro êdá àmútõrun wá ni.
ÈDÈ

11. Ìrókíròó tí a bá pè nígbà ti ìdíwö wà fún èémí ni

A. fáwêlì    B. köþsónáýtì    C. ìró-ohùn    D. ìró-ìfõ.


12. Fi àmì-ohùn tó tõnà sórí Olubôbôtiribô láti fún un ní ìtumõ tó péye.

A. Olúböbôtiribö    B. Olùböbôtìribö    C. Olúbõbõtiribõ    D. Olùbõbôtíribõ


13. Õrõ wo ni kò ní apààlà sílébù nínú Olú á ra bàtà?

A. Olú    B. á    C. ra    D. bàtà.


14. Dá iná di Dáná nípasê

A. ìyöpõ    B. àrànmö    C. àýkóò fáwêlì    D. ìpajç fáwêlì.


15. Àpççrç õrõ àyálò níbi tí köþsónáýtì ti parí õrõ ni

A. máþgòrò    B. töõgì    C. biro    D. búlúù.


16. Õrõ-aröpò-orúkô çnì kìíní õpõ ní ipò àbõ ni

A. wa    B. wôn    C. yin    D. òun.


17. ‘Ìwô ni’ Nínú gbólóhùn yìí, ni jë õrõ

A. atökùn    B. orúkô    C. ìÿe    D. àpèjúwe.


18. ‘Owó tí mo yá tán’ Irú awë-gbólóhùn wo ni tí mo yá?

A. Aÿàlàyé    B. Aÿàpèjúwe    C. Aÿòýkà    D. Aláfibõ.


19. ‘Një o gbö kí o panumö’, jë gbólóhùn

A. àlàyé    B. àÿç    C. ibá ìÿêlê    D. kání.


20. Gbólóhùn tó fi àsìkò afànámónìí hàn ni

A. ó máa lô sí Èkó
B. ó lô sí Èkó
C. ó máa þ lô sí Èkó
D. ó ti lô sí Èkó


21. Ète môfölõjì tí a lò láti ÿêdá ômôkömô ni

A. àpètúnpè
B. àpètúnpè pêlú àfòmö-ìbêrê
C. àkànpõ
D. àpètúnpè pêlú àfòmö-ààrin.


22. Àtúnkô fún Adé na Olú nípa lílo õrõ-aröpò-orúkô dípò Olú ni

A. Adé nà á    B. Adé nà án    C. Adé nà-án    D. Adé nà-á.


23. Éwo ló bá ìlànà àkôtö òde-òní mu?

A. Ìbà jë ômô ènìyàn kò dá iÿë Olúwa dúró
B. Ìbáàjë ômô ènìyàn kò dá iÿë Olúwa dúró
C. Ìbàjë ômô ènìyàn kò dá iÿë Olúwa dúró
D. Ìbàjë ômô ènìyàn kòdá iÿë Olúwa dúró.


24. ße ìtumõ ‘Uneasy lies the head that wears a crown’.

A. Õpõlôpõ ìdààmú wà lórí tó dé adé
B. Õpõlõpõ wàhálà ló rõ mö ipò olórí
C. Õpõlôpõ ìdààmú ló ÿe àtakò olórí
D. Õpõlôpõ wàhálà dúró lórí tó dé adé


25. ße ìtumõ ‘I am at my wits’ end on this issue’.

A. Ìjìnlê èrò mi tán nípa õrõ yìí
B. Ôgbön mi ti pin lórí õrõ yìí
C. Mo ti dé ìparí èrò ôkàn mi lórí õrõ yìí
D. N ò mô ohun tí mo lè ÿe mö lórí õrõ yìí
ÌßÊßE

26. Òdiwõn ojúgbà láàrin ìlú ni

A. yíyagìrìpá    B. agbára    C. ôjö orí    D. ôlá.


27. Õkan lára ohun-èlò ti Yorùbá fi máa þ ÿe õÿö sí ara ômô tuntun ni

A. làálì    B. òrí    C. osùn    D. bùjé.


28. ‘Tìpêtipç-n-tìrán:
Ikun imú arúgbó kì í já bõrõbõrõ
Tìpêtipç-n-tìrán’.

Ibi eré ìdárayá wo ni a ti sábà máa þ gbó ìpèdè òkè yìí?

A. Ìgbò-jíjà    B. Kànnàkànnà    C. Òkìtì    D. Çkç


29. Dídi õbç ìfárí mö òkú löwö sínú sàréè töka sí òkú

A. ìjàngbòn    B. awo    C. ríró    D. òrìÿà


30. Àwôn Yorùbá máa þ lo ewé efinrin fún

A. jêdíjêdí    B. jêdõjêdõ    C. çförí túúlu    D. àgbo emèrè.


31. Çgbë awo tó þ kópa pàtàkì nínú ètò ìÿèlú láyé àtijö ni

A. ifá    B. àjë    C. ògbóni    D. egúngún


32. Òrìÿà ti àwôn Yorùbá gbàgbö pé ó jé àpççrç àwôn baba-þlá tó ti kú ni

A. Ìgunnu    B. Òrìÿà-nlá    C. Eégún    D. Ayélála.


33. Iÿë àwôn òbí nínú ètò ìgbéyàwó ni

A. ìjöhçn    B. ìwádìí    C. aÿô rírà    D. eyín pípa.


34. Ààbõ agbè çmu ti a fi ÿôwö sí òbí ìyàwó lëyìn ìgbéyàwó túmõ sí

A. íÿíhùn
B. ìdána
C. pé ìyàwó tí lóyún kó tó wôlékô
D. pé ìyàwó ti sô ìbálé nù.


35. Ká ní õyàyà, ká kóni möra, ká sì ÿe ohun tó tö ní ìwà

A. adémêtö    B. ômôlúwàbí    C. ìfë    D. ìranraçnilöwö.

GREAT! You finished before the expiration of the 20 minutes allotted to you. You may want to preview before submission, else, Click the submit button below to see your score

To submit your quiz and see your score/performance report; Make sure you supply your Full Name in the form above.

Unable to submit your quiz? Kindly Click Here To Retake UTME CBT FREE Practice Test - Yoruba Language - Set 1. Make sure you supply your Full Name before submission.Online Learning and Assessment Portal for Nigerian and International Students
error: Content is protected !!